-
Jóòbù 3:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Kí ló dé tó fún ẹni tó ṣìnà ní ìmọ́lẹ̀,
Ẹni tí Ọlọ́run ti sé mọ́?+
-
-
Sáàmù 88:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 O ti lé àwọn ojúlùmọ̀ mi jìnnà réré sí mi;+
O ti sọ mí di ohun ìríra sí wọn.
Mo ti kó sí pańpẹ́, mi ò sì lè jáde.
-