-
Jóòbù 8:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí gbogbo àwọn tó gbàgbé Ọlọ́run nìyẹn,*
Torí ìrètí ẹni tí kò mọ Ọlọ́run* máa ṣègbé,
-
Jóòbù 21:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Torí ẹ sọ pé, ‘Ibo ni ilé ẹni tó gbajúmọ̀ wà,
Ibo sì ni àgọ́ tí ẹni burúkú gbé wà?’+
-
-
-