Jóòbù 8:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí gbogbo àwọn tó gbàgbé Ọlọ́run nìyẹn,*Torí ìrètí ẹni tí kò mọ Ọlọ́run* máa ṣègbé, Jóòbù 8:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Àmọ́ tí wọ́n bá ti fà á tu* kúrò níbi tó wà,Ibẹ̀ máa kọ̀ ọ́ sílẹ̀, ó sì máa sọ fún un pé, ‘Mi ò rí ọ rí.’+
13 Ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí gbogbo àwọn tó gbàgbé Ọlọ́run nìyẹn,*Torí ìrètí ẹni tí kò mọ Ọlọ́run* máa ṣègbé, Jóòbù 8:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Àmọ́ tí wọ́n bá ti fà á tu* kúrò níbi tó wà,Ibẹ̀ máa kọ̀ ọ́ sílẹ̀, ó sì máa sọ fún un pé, ‘Mi ò rí ọ rí.’+
18 Àmọ́ tí wọ́n bá ti fà á tu* kúrò níbi tó wà,Ibẹ̀ máa kọ̀ ọ́ sílẹ̀, ó sì máa sọ fún un pé, ‘Mi ò rí ọ rí.’+