-
Jóòbù 15:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Etí rẹ̀ ń gbọ́ àwọn ìró tó ń bani lẹ́rù;+
Nígbà àlàáfíà, àwọn tó ń kóni lẹ́rù dìde sí i.
-
-
Jóòbù 18:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Àní, a máa pa iná ẹni burúkú,
Ọwọ́ iná rẹ̀ kò sì ní tàn.+
-
-
Jóòbù 18:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Jìnnìjìnnì bò ó yí ká,+
Ó sì ń sá tẹ̀ lé e ní ẹsẹ̀ rẹ̀.
-