-
Sáàmù 10:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Ìgbéraga kì í jẹ́ kí ẹni burúkú ṣe ìwádìí kankan;
Gbogbo èrò rẹ̀ ni pé: “Kò sí Ọlọ́run.”+
-
-
Hósíà 13:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Torí náà, wọ́n gbàgbé mi.+
-