Sáàmù 11:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Yóò dẹ ọ̀pọ̀ pańpẹ́ fún* àwọn ẹni burúkú;Iná, imí ọjọ́+ àti ẹ̀fúùfù gbígbóná ni yóò wà nínú ife wọn. Àìsáyà 26:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Jèhófà, ọwọ́ rẹ wà lókè, ṣùgbọ́n wọn ò rí i.+ Wọ́n máa rí ìtara tí o ní fún àwọn èèyàn rẹ, ojú á sì tì wọ́n. Àní, iná tó wà fún àwọn ọ̀tá rẹ máa jó wọn run.
6 Yóò dẹ ọ̀pọ̀ pańpẹ́ fún* àwọn ẹni burúkú;Iná, imí ọjọ́+ àti ẹ̀fúùfù gbígbóná ni yóò wà nínú ife wọn.
11 Jèhófà, ọwọ́ rẹ wà lókè, ṣùgbọ́n wọn ò rí i.+ Wọ́n máa rí ìtara tí o ní fún àwọn èèyàn rẹ, ojú á sì tì wọ́n. Àní, iná tó wà fún àwọn ọ̀tá rẹ máa jó wọn run.