Àìsáyà 40:13, 14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ta ló ti díwọ̀n* ẹ̀mí Jèhófà,Ta ló sì lè dá a lẹ́kọ̀ọ́ gẹ́gẹ́ bí agbani-nímọ̀ràn rẹ̀?+ 14 Ta ló ti bá fikùn lukùn kó lè ní òye,Tàbí ta ló kọ́ ọ ní ọ̀nà ìdájọ́ òdodo,Tó kọ́ ọ ní ìmọ̀,Tàbí tó fi ọ̀nà òye tòótọ́ hàn án?+ Róòmù 11:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Nítorí “ta ló mọ èrò Jèhófà,* ta sì ni agbani-nímọ̀ràn rẹ̀?”+ 1 Kọ́ríńtì 2:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nítorí “ta ló ti wá mọ èrò inú Jèhófà,* kí ó lè kọ́ ọ lẹ́kọ̀ọ́?”+ Àmọ́ àwa ní èrò inú Kristi.+
13 Ta ló ti díwọ̀n* ẹ̀mí Jèhófà,Ta ló sì lè dá a lẹ́kọ̀ọ́ gẹ́gẹ́ bí agbani-nímọ̀ràn rẹ̀?+ 14 Ta ló ti bá fikùn lukùn kó lè ní òye,Tàbí ta ló kọ́ ọ ní ọ̀nà ìdájọ́ òdodo,Tó kọ́ ọ ní ìmọ̀,Tàbí tó fi ọ̀nà òye tòótọ́ hàn án?+