-
Sáàmù 18:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Nítorí mo ti pa àwọn ọ̀nà Jèhófà mọ́,
Mi ò hùwà burúkú, kí n wá fi Ọlọ́run mi sílẹ̀.
-
-
Sáàmù 44:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Ọkàn wa kò kúrò lọ́dọ̀ rẹ;
Ẹsẹ̀ wa kò yà kúrò ní ọ̀nà rẹ.
-