Jóòbù 9:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ọlọ́run ò ní dáwọ́ ìbínú rẹ̀ dúró;+Àwọn tó ń ran Ráhábù*+ lọ́wọ́ pàápàá máa tẹrí ba fún un.