-
Sáàmù 18:37Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
37 Màá lépa àwọn ọ̀tá mi, màá sì bá wọn;
Mi ò ní pa dà títí wọ́n á fi pa rẹ́.
-
-
Sáàmù 18:41Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
41 Wọ́n kígbe fún ìrànlọ́wọ́, àmọ́ kò sí ẹni tó máa gbà wọ́n;
Kódà, wọ́n ké pe Jèhófà, àmọ́ kò dá wọn lóhùn.
-
-
Jémíìsì 4:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Nígbà tí ẹ sì béèrè, ẹ ò rí gbà torí ohun tí kò dáa lẹ fẹ́ fi ṣe, ṣe lẹ fẹ́ lò ó fún ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ara yín.
-