Mátíù 7:26, 27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Bákan náà, gbogbo ẹni tó gbọ́ ọ̀rọ̀ mi yìí, tí kò sì ṣe é máa dà bí òmùgọ̀ ọkùnrin tó kọ́ ilé rẹ̀ sórí iyanrìn.+ 27 Òjò sì rọ̀, omi kún àkúnya, ìjì sì fẹ́ lu ilé náà,+ àmọ́ kò lè dúró, ńṣe ló wó lulẹ̀ bẹẹrẹbẹ.”
26 Bákan náà, gbogbo ẹni tó gbọ́ ọ̀rọ̀ mi yìí, tí kò sì ṣe é máa dà bí òmùgọ̀ ọkùnrin tó kọ́ ilé rẹ̀ sórí iyanrìn.+ 27 Òjò sì rọ̀, omi kún àkúnya, ìjì sì fẹ́ lu ilé náà,+ àmọ́ kò lè dúró, ńṣe ló wó lulẹ̀ bẹẹrẹbẹ.”