Sáàmù 83:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Bẹ́ẹ̀ ni kí o fi ìjì líle rẹ lépa wọn,+Kí o sì fi ẹ̀fúùfù rẹ kó jìnnìjìnnì bá wọn.+