-
Diutarónómì 8:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 ilẹ̀ tí oúnjẹ ò ti ní wọ́n ọ, tó ò sì ní ṣaláìní ohunkóhun, ilẹ̀ tí irin wà nínú àwọn òkúta rẹ̀, tí wàá sì máa wa bàbà látinú àwọn òkè rẹ̀.
-