Òwe 3:13, 14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Aláyọ̀ ni ẹni tó wá ọgbọ́n rí+Àti ẹni tó ní òye;14 Kéèyàn ní in sàn ju kéèyàn ní fàdákà,Kéèyàn jèrè rẹ̀ sì sàn ju kéèyàn jèrè wúrà.+
13 Aláyọ̀ ni ẹni tó wá ọgbọ́n rí+Àti ẹni tó ní òye;14 Kéèyàn ní in sàn ju kéèyàn ní fàdákà,Kéèyàn jèrè rẹ̀ sì sàn ju kéèyàn jèrè wúrà.+