Òwe 16:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ó mà sàn kéèyàn ní ọgbọ́n ju kó ní wúrà o!+ Ó sì dára kéèyàn ní òye ju kó ní fàdákà.+