-
Sáàmù 58:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ọlọ́run, gbá eyín wọn yọ kúrò lẹ́nu wọn!
Fọ́ páárì ẹ̀rẹ̀kẹ́ àwọn kìnnìún yìí,* Jèhófà!
-
-
Òwe 30:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Ìran kan wà tí eyín rẹ̀ jẹ́ idà,
Egungun páárì ẹ̀rẹ̀kẹ́ rẹ̀ sì jẹ́ ọ̀bẹ ìpẹran;
Wọ́n ń jẹ àwọn aláìní inú ayé run
Wọ́n sì ń jẹ àwọn òtòṣì run láàárín aráyé.+
-