-
Sáàmù 69:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Èmi ni àwọn tó ń jókòó ní ẹnubodè fi ń ṣe ọ̀rọ̀ sọ,
Ọ̀rọ̀ mi sì ni àwọn ọ̀mùtí fi ń ṣe orin kọ.
-
-
Ìdárò 3:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Mo ti di ẹni yẹ̀yẹ́ lójú gbogbo èèyàn, ọ̀rọ̀ mi sì ni wọ́n fi ń ṣe orin kọ láti àárọ̀ ṣúlẹ̀.
-