Jóòbù 31:9, 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Tí ọkàn mi bá ti fà sí obìnrin kan,+Tí mo sì lúgọ+ sẹ́nu ọ̀nà ọmọnìkejì mi,10 Kí ìyàwó mi lọ ọkà fún ọkùnrin míì,Kí àwọn ọkùnrin míì sì bá a lò pọ̀.*+
9 Tí ọkàn mi bá ti fà sí obìnrin kan,+Tí mo sì lúgọ+ sẹ́nu ọ̀nà ọmọnìkejì mi,10 Kí ìyàwó mi lọ ọkà fún ọkùnrin míì,Kí àwọn ọkùnrin míì sì bá a lò pọ̀.*+