Sáàmù 139:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Kódà, ojú rẹ rí mi nígbà tí mo ṣì wà nínú ikùn;*Gbogbo àwọn ẹ̀yà rẹ̀ wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé rẹNí ti àwọn ọjọ́ tí o ṣẹ̀dá wọn,Kí ìkankan lára wọn tó wà.
16 Kódà, ojú rẹ rí mi nígbà tí mo ṣì wà nínú ikùn;*Gbogbo àwọn ẹ̀yà rẹ̀ wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé rẹNí ti àwọn ọjọ́ tí o ṣẹ̀dá wọn,Kí ìkankan lára wọn tó wà.