-
Sáàmù 62:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Ẹ má rò pé lílọ́ni lọ́wọ́ gbà máa mú kí ẹ ṣàṣeyọrí,
Ẹ má sì rò pé olè jíjà máa ṣe yín láǹfààní.
Tí ọrọ̀ yín bá ń pọ̀ sí i, ẹ má ṣe gbọ́kàn lé e.+
-