-
Jóòbù 10:2, 3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Màá sọ fún Ọlọ́run pé: ‘Má ṣe dá mi lẹ́bi.
Jẹ́ kí n mọ ìdí tí o fi ń bá mi jà.
3 Ṣé ó máa ṣe ọ́ láǹfààní tí o bá fìyà jẹni,
Tí o bá kórìíra iṣẹ́ ọwọ́ rẹ,+
Tí o sì fara mọ́ ìmọ̀ràn àwọn ẹni burúkú?
-