-
Jóòbù 13:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 O ti ẹsẹ̀ mi mọ́ inú àbà,
Ò ń ṣọ́ gbogbo ọ̀nà mi lójú méjèèjì,
O sì ń wá ipasẹ̀ mi jáde lọ́kọ̀ọ̀kan.
-
-
Jóòbù 14:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Àmọ́ ní báyìí, ò ń ka gbogbo ìṣísẹ̀ mi ṣáá;
Ẹ̀ṣẹ̀ mi nìkan lò ń ṣọ́.
-
-
Jóòbù 31:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Ṣebí ó ń rí àwọn ọ̀nà mi,+
Tó sì ń ka gbogbo ìṣísẹ̀ mi?
-