Jóòbù 19:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Torí ó dá mi lójú pé olùràpadà*+ mi wà láàyè;Ó máa wá tó bá yá, ó sì máa dìde lórí ayé.* Mátíù 20:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Gẹ́gẹ́ bí Ọmọ èèyàn ò ṣe wá ká lè ṣe ìránṣẹ́ fún un, àmọ́ kó lè ṣe ìránṣẹ́,+ kó sì fi ẹ̀mí* rẹ̀ ṣe ìràpadà ní pàṣípààrọ̀ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn.”+
28 Gẹ́gẹ́ bí Ọmọ èèyàn ò ṣe wá ká lè ṣe ìránṣẹ́ fún un, àmọ́ kó lè ṣe ìránṣẹ́,+ kó sì fi ẹ̀mí* rẹ̀ ṣe ìràpadà ní pàṣípààrọ̀ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn.”+