-
Jóòbù 9:17, 18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Torí ó fi ìjì wó mi mọ́lẹ̀,
Ó sì mú kí ọgbẹ́ mi pọ̀ sí i láìnídìí.+
18 Kò jẹ́ kí n mí;
Ó ń fi àwọn ohun tó korò kún inú mi.
-