-
Jémíìsì 1:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Tí àdánwò bá dé bá ẹnikẹ́ni, kó má ṣe sọ pé: “Ọlọ́run ló ń dán mi wò.” Torí a ò lè fi ibi dán Ọlọ́run wò, òun náà kì í sì í dán ẹnikẹ́ni wò.
-