1 Sámúẹ́lì 15:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “Ó dùn mí* pé mo fi Sọ́ọ̀lù jọba, torí ó ti pa dà lẹ́yìn mi, kò sì ṣe ohun tí mo sọ.”+ Inú Sámúẹ́lì bà jẹ́ gan-an, ó sì ń ké pe Jèhófà láti òru mọ́jú.+
11 “Ó dùn mí* pé mo fi Sọ́ọ̀lù jọba, torí ó ti pa dà lẹ́yìn mi, kò sì ṣe ohun tí mo sọ.”+ Inú Sámúẹ́lì bà jẹ́ gan-an, ó sì ń ké pe Jèhófà láti òru mọ́jú.+