Ẹ́kísódù 22:22, 23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 “Ẹ ò gbọ́dọ̀ fìyà jẹ opó tàbí ọmọ aláìníbaba* kankan.+ 23 Tí ẹ bá fìyà jẹ ẹ́ pẹ́nrẹ́n, tó sì ké pè mí, ó dájú pé màá gbọ́ igbe rẹ̀;+ Jémíìsì 5:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Wò ó! Owó iṣẹ́ tí ẹ ò san fún àwọn òṣìṣẹ́ tó kórè oko yín ń ké jáde ṣáá, igbe tí àwọn olùkórè ń ké fún ìrànwọ́ sì ti dé etí Jèhófà* Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.+
22 “Ẹ ò gbọ́dọ̀ fìyà jẹ opó tàbí ọmọ aláìníbaba* kankan.+ 23 Tí ẹ bá fìyà jẹ ẹ́ pẹ́nrẹ́n, tó sì ké pè mí, ó dájú pé màá gbọ́ igbe rẹ̀;+
4 Wò ó! Owó iṣẹ́ tí ẹ ò san fún àwọn òṣìṣẹ́ tó kórè oko yín ń ké jáde ṣáá, igbe tí àwọn olùkórè ń ké fún ìrànwọ́ sì ti dé etí Jèhófà* Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.+