ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóòbù 35:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Jóòbù kàn ń la ẹnu lásán ni;

      Ó sọ̀rọ̀ púpọ̀ láìní ìmọ̀.”+

  • Jóòbù 38:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 “Ta lẹni yìí tí kò jẹ́ kí ìmọ̀ràn mi ṣe kedere,

      Tó ń sọ̀rọ̀ láìní ìmọ̀?+

  • Jóòbù 42:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 O sọ pé, ‘Ta lẹni yìí tí kò jẹ́ kí ìmọ̀ràn mi ṣe kedere, tí kò ní ìmọ̀?’+

      Torí náà, mo sọ̀rọ̀, àmọ́ mi ò lóye,

      Nípa àwọn ohun tó yà mí lẹ́nu gidigidi, tí mi ò mọ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́