Sáàmù 31:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ṣojú rere sí mi, Jèhófà, torí mo wà nínú ìdààmú. Ìrora ti sọ ojú mi di bàìbàì,+ àárẹ̀ sì ti bá gbogbo ara mi.*+
9 Ṣojú rere sí mi, Jèhófà, torí mo wà nínú ìdààmú. Ìrora ti sọ ojú mi di bàìbàì,+ àárẹ̀ sì ti bá gbogbo ara mi.*+