Sáàmù 33:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Wò ó! Ojú Jèhófà ń ṣọ́ àwọn tó bẹ̀rù rẹ̀,+Àwọn tó ń dúró de ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀, Sáàmù 34:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ojú Jèhófà wà lára àwọn olódodo,+Etí rẹ̀ sì ṣí sí igbe wọn fún ìrànlọ́wọ́.+
18 Wò ó! Ojú Jèhófà ń ṣọ́ àwọn tó bẹ̀rù rẹ̀,+Àwọn tó ń dúró de ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀, Sáàmù 34:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ojú Jèhófà wà lára àwọn olódodo,+Etí rẹ̀ sì ṣí sí igbe wọn fún ìrànlọ́wọ́.+