Àìsáyà 40:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ta ló ti bá fikùn lukùn kó lè ní òye,Tàbí ta ló kọ́ ọ ní ọ̀nà ìdájọ́ òdodo,Tó kọ́ ọ ní ìmọ̀,Tàbí tó fi ọ̀nà òye tòótọ́ hàn án?+
14 Ta ló ti bá fikùn lukùn kó lè ní òye,Tàbí ta ló kọ́ ọ ní ọ̀nà ìdájọ́ òdodo,Tó kọ́ ọ ní ìmọ̀,Tàbí tó fi ọ̀nà òye tòótọ́ hàn án?+