2 Sámúẹ́lì 22:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Nígbà náà, Jèhófà bẹ̀rẹ̀ sí í sán ààrá láti ọ̀run;+Ẹni Gíga Jù Lọ mú kí a gbọ́ ohùn rẹ̀.+