Ìfihàn 22:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “‘Èmi Jésù rán áńgẹ́lì mi láti jẹ́rìí àwọn nǹkan yìí fún ọ nítorí àwọn ìjọ. Èmi ni gbòǹgbò àti ọmọ Dáfídì+ àti ìràwọ̀ òwúrọ̀ tó mọ́lẹ̀ rekete.’”+
16 “‘Èmi Jésù rán áńgẹ́lì mi láti jẹ́rìí àwọn nǹkan yìí fún ọ nítorí àwọn ìjọ. Èmi ni gbòǹgbò àti ọmọ Dáfídì+ àti ìràwọ̀ òwúrọ̀ tó mọ́lẹ̀ rekete.’”+