Òwe 3:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ọgbọ́n ni Jèhófà fi dá ayé.+ Òye ni ó fi fìdí ọ̀run múlẹ̀ gbọn-in.+ Jeremáyà 31:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,Ẹni tó ń mú kí oòrùn máa tan ìmọ́lẹ̀ ní ọ̀sán,Tó sì ṣe òfin* pé kí òṣùpá àti àwọn ìràwọ̀ máa tàn ní òru,Ẹni tó ń ru òkun sókè, tó sì ń mú kí ìgbì rẹ̀ máa pariwo,Ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun:+ Jeremáyà 33:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: ‘Bí mo ṣe fìdí májẹ̀mú mi nípa ọ̀sán àti òru múlẹ̀+ àti òfin* nípa ọ̀run àti ayé,+
35 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,Ẹni tó ń mú kí oòrùn máa tan ìmọ́lẹ̀ ní ọ̀sán,Tó sì ṣe òfin* pé kí òṣùpá àti àwọn ìràwọ̀ máa tàn ní òru,Ẹni tó ń ru òkun sókè, tó sì ń mú kí ìgbì rẹ̀ máa pariwo,Ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun:+
25 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: ‘Bí mo ṣe fìdí májẹ̀mú mi nípa ọ̀sán àti òru múlẹ̀+ àti òfin* nípa ọ̀run àti ayé,+