-
Sáàmù 29:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Ohùn Jèhófà kó jìnnìjìnnì bá àwọn àgbọ̀nrín, wọ́n sì bímọ,
Bákan náà, ó ń tú àwọn igbó kìjikìji sí borokoto.+
Gbogbo àwọn tó wà nínú tẹ́ńpìlì rẹ̀ sì sọ pé: “Ògo!”
-