-
Jóòbù 24:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Àwọn aláìní ń wá oúnjẹ kiri bíi kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ igbó+ nínú aginjù;
Wọ́n ń wá oúnjẹ kiri fún àwọn ọmọ wọn nínú aṣálẹ̀.
-
-
Sáàmù 104:10, 11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Ó ń mú kí omi sun jáde ní àwọn àfonífojì;
Wọ́n ń ṣàn gba àárín àwọn òkè.
11 Wọ́n ń pèsè omi fún gbogbo ẹran inú igbó;
Àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ igbó ń fi wọ́n pa òùngbẹ.
-