ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 5:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Gbogbo ọfà wọn mú,

      Wọ́n sì ti fa gbogbo ọrun wọn.*

      Pátákò àwọn ẹṣin wọn dà bí akọ òkúta,

      Àwọn àgbá kẹ̀kẹ́ wọn sì dà bí ìjì.+

  • Jeremáyà 8:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Mo fiyè sí wọn, mo sì ń fetí sílẹ̀, àmọ́ bí wọ́n ṣe sọ̀rọ̀ kò dáa.

      Kò sí ẹnì kankan tó ronú pìwà dà ìwà burúkú rẹ̀ tàbí kó sọ pé, ‘Kí ni mo ṣe yìí?’+

      Kálukú wọn ń pa dà lọ ṣe ohun tí ọ̀pọ̀ èèyàn ń ṣe, bí ẹṣin tó ń já lọ sójú ogun.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́