-
Jóòbù 9:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Wọ́n ń yára bí ọkọ̀ ojú omi tí wọ́n fi esùsú* ṣe,
Bí ẹyẹ idì tó já ṣòòrò wálẹ̀ láti gbé ohun tó fẹ́ pa.
-
-
Jeremáyà 49:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Ní ọjọ́ yẹn, ọkàn àwọn jagunjagun Édómù
Máa dà bí ọkàn obìnrin tó ń rọbí.”
-