ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóòbù 13:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Ní tèmi, màá kúkú bá Olódùmarè fúnra rẹ̀ sọ̀rọ̀;

      Ọlọ́run ni mo fẹ́ ro ẹjọ́ mi fún.+

  • Jóòbù 23:3-5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Ká ní mo mọ ibi tí mo ti lè rí Ọlọ́run ni!+

      Ǹ bá lọ sí ibùgbé rẹ̀.+

       4 Màá ro ẹjọ́ mi níwájú rẹ̀,

      Màá sì fi gbogbo ẹnu mi gbèjà ara mi;

       5 Màá fetí sí ìdáhùn tó bá fún mi,

      Màá sì fọkàn sí ohun tó bá sọ fún mi.

  • Jóòbù 31:35
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 35 Ká ní ẹnì kan lè fetí sí mi ni!+

      Ǹ bá buwọ́ lùwé sí ohun tí mo sọ.*

      Kí Olódùmarè dá mi lóhùn!+

      Ká ní ẹni tó fẹ̀sùn kàn mí ti kọ ẹ̀sùn náà sínú ìwé ni!

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́