Jóòbù 30:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Awọ ara mi ti dúdú, ó sì ti re dà nù;+Ooru* ti mú kí egungun mi gbóná.