ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 27:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Nígbà tó di àárọ̀, gbogbo àwọn olórí àlùfáà àti àwọn àgbààgbà àwọn èèyàn náà gbìmọ̀ pọ̀ kí wọ́n lè pa Jésù.+ 2 Lẹ́yìn tí wọ́n dè é, wọ́n mú un lọ, wọ́n sì fà á lé Pílátù lọ́wọ́, òun ni gómìnà.+

  • Lúùkù 23:10, 11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Síbẹ̀, àwọn olórí àlùfáà àti àwọn akọ̀wé òfin ń dìde ṣáá, wọ́n sì ń fẹ̀sùn kàn án kíkankíkan. 11 Hẹ́rọ́dù àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ wá kàn án lábùkù,+ ó wọ aṣọ tó rẹwà fún un láti fi ṣe ẹlẹ́yà,+ ó sì ní kí wọ́n mú un pa dà sọ́dọ̀ Pílátù.

  • Ìfihàn 19:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Mo sì rí i tí ẹranko náà àti àwọn ọba ayé pẹ̀lú àwọn ọmọ ogun wọn kóra jọ láti bá ẹni tó jókòó sórí ẹṣin àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ jagun.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́