Míkà 7:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ó tún máa ṣàánú wa;+ ó sì máa pa àwọn àṣìṣe wa rẹ́.* O máa ju gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wọn sí ìsàlẹ̀ òkun.+