Jeremáyà 32:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Màá fún wọn ní ọkàn kan+ àti ọ̀nà kan kí wọ́n lè máa bẹ̀rù mi nígbà gbogbo, fún ire wọn àti ti àwọn ọmọ wọn lẹ́yìn wọn.+
39 Màá fún wọn ní ọkàn kan+ àti ọ̀nà kan kí wọ́n lè máa bẹ̀rù mi nígbà gbogbo, fún ire wọn àti ti àwọn ọmọ wọn lẹ́yìn wọn.+