Ìsíkíẹ́lì 11:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Èmi yóò mú kí ọkàn wọn ṣọ̀kan,*+ màá sì fi ẹ̀mí tuntun sínú wọn;+ màá mú ọkàn òkúta kúrò lára wọn,+ màá sì fún wọn ní ọkàn ẹran,*+ Éfésù 4:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Torí náà, ẹ máa di tuntun nínú agbára tó ń darí ìrònú yín,*+
19 Èmi yóò mú kí ọkàn wọn ṣọ̀kan,*+ màá sì fi ẹ̀mí tuntun sínú wọn;+ màá mú ọkàn òkúta kúrò lára wọn,+ màá sì fún wọn ní ọkàn ẹran,*+