-
Sáàmù 34:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 Èmi yóò máa yin Jèhófà ní gbogbo ìgbà;
Ìyìn rẹ̀ yóò máa wà ní ẹnu mi nígbà gbogbo.
-
-
Sáàmù 109:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Ẹnu mi á máa yin Jèhófà gidigidi;
Màá máa yìn ín níwájú ọ̀pọ̀ èèyàn.+
-