Sáàmù 27:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà;+Ní ìgboyà, kí o sì mọ́kàn le.+ Bẹ́ẹ̀ ni, gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà. Sáàmù 123:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Bí ojú àwọn ìránṣẹ́ ṣe ń wo ọwọ́ ọ̀gá wọnÀti bí ojú ìránṣẹ́bìnrin ṣe ń wo ọwọ́ ọ̀gá rẹ̀ obìnrin,Bẹ́ẹ̀ ni ojú wa ń wo Jèhófà Ọlọ́run wa,+Títí á fi ṣojú rere sí wa.+ Òwe 18:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Orúkọ Jèhófà jẹ́ ilé gogoro tó lágbára.+ Olódodo sá wọ inú rẹ̀, ó sì rí ààbò.*+
2 Bí ojú àwọn ìránṣẹ́ ṣe ń wo ọwọ́ ọ̀gá wọnÀti bí ojú ìránṣẹ́bìnrin ṣe ń wo ọwọ́ ọ̀gá rẹ̀ obìnrin,Bẹ́ẹ̀ ni ojú wa ń wo Jèhófà Ọlọ́run wa,+Títí á fi ṣojú rere sí wa.+