-
Sáàmù 10:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Ìgbéraga kì í jẹ́ kí ẹni burúkú ṣe ìwádìí kankan;
Gbogbo èrò rẹ̀ ni pé: “Kò sí Ọlọ́run.”+
-
-
Róòmù 1:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Nítorí bó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n mọ Ọlọ́run, wọn ò yìn ín lógo bí Ọlọ́run, bẹ́ẹ̀ ni wọn ò dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀, ìrònú wọn ò mọ́gbọ́n dání, ọkàn wọn tó ti kú tipiri sì ṣókùnkùn.+
-