-
Oníwàásù 7:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Nítorí kò sí olódodo kankan láyé tó ń ṣe rere nígbà gbogbo tí kì í dẹ́ṣẹ̀.+
-
-
Róòmù 3:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Gbogbo èèyàn ti fi ọ̀nà sílẹ̀, gbogbo wọn ti di aláìníláárí; kò sí ẹnì kankan tó ń ṣoore, kò tiẹ̀ sí ẹyọ kan.”+
-