-
1 Kíróníkà 12:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Ìgbà náà ni ẹ̀mí Ọlọ́run bà lé Ámásáì,*+ olórí ọgbọ̀n ọmọ ogun, ó ní:
“Tìrẹ ni wá, Dáfídì, ọ̀dọ̀ rẹ sì ni a wà, ìwọ ọmọ Jésè.+
Àlàáfíà, àlàáfíà fún ọ, àlàáfíà fún ẹni tó ń ràn ọ́ lọ́wọ́,
Nítorí Ọlọ́run rẹ ń ràn ọ́ lọ́wọ́.”+
Torí náà, Dáfídì gbà wọ́n, ó sì yàn wọ́n pé kí wọ́n wà lára àwọn olórí ọmọ ogun.
-