Àìsáyà 38:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Mò ń ké ṣíoṣío bí ẹyẹ olófèéèré àti ẹ̀gà;*+Mò ń ké kúùkúù bí àdàbà.+ Ojú mi ń wo ibi gíga títí ó fi rẹ̀ mí:+ ‘Jèhófà, ìdààmú ti bò mí mọ́lẹ̀;Ràn mí lọ́wọ́!’*+
14 Mò ń ké ṣíoṣío bí ẹyẹ olófèéèré àti ẹ̀gà;*+Mò ń ké kúùkúù bí àdàbà.+ Ojú mi ń wo ibi gíga títí ó fi rẹ̀ mí:+ ‘Jèhófà, ìdààmú ti bò mí mọ́lẹ̀;Ràn mí lọ́wọ́!’*+